Mojùbá Olòdúmaré

Paulo Chagas

Composed by: Paulo Chagas Ferreira
Mojúbà Olódúmarè (4x)
Mojúbà Baba mi Olódúmarè
Mojúbà Baba mi Olòrun
Mojúbà Baba mi Olódúmarè
Mojúbà Baba mi Olòfin

Mojúbà Àkódá
Mojúbà Asèdá

Mojúbà Ilè-Ògéré
Mojúbà Ilè-Àiyé

Mojúbà Ìlà-òrùn
Mojúbà Ìwò-òrùn
Mojúbà Àrìwà
Mojúbà Gúúsù

Mojúbà Ajaí-odún
Mojúbà Oní-odún
Mojúbà Odún-olá

Mojúbà Baba
Mojúbà Yeye
    Page 1 / 1

    Lyrics and title
    Chords and artist

    reset settings
    OK