Ó fúruru lóòréré o
Àilaá bàbá kenyenyen l'éjgbó
Ilé Ifon mo ti wá bàbá
Èjìgbò réré mojubá ô
Oluwá ema woró, ema woró alé sé

Eyà wá wòrò
Ewa wése!
E ma wá woró elésè kan bàbá
Eyà wá wòrò
Ewa wése!
    Page 1 / 1

    Lyrics and title
    Chords and artist

    reset settings
    OK